
Author: Henry F. Lyte; Anonymous Meter: 7.7.7.7 D Appears in 1 hymnal First Line: Bugbe Re ti l’ewa to! Lyrics: 1 Bugbe Re ti l’ewa to!
N’ ile mole at’ ife,
Bugbe Re ti l’ewa to!
Laiye ese at’ osi.
Okan mi n fa ni to to
Fun idapo enia Re
Fun imole oju Re
Fun ekun Re Olorun
2 A yo ba awon eiye
Ti nfo yi pepe Re ka;
Ayo okan t’o simi
L’aiya Baba l’o poju!
Gege b’adaba Noa
Ti ko r’ibi simi le,
Nwon pada sodo Baba
Nwon si nyo titi aiye
3 Nwon ko simi iyin won,
Ninu aiye osi yi;
Omi nsun ni aginju,
Manna nt’orun wa fun won,
Nwon nlo lat’ipa de’pa,
Titi nwon fi yo si O;
Nwon si wole l’ese Re,
T’o mu won la ewu ja.
4 Baba je ki njere be
S’amona mi laiye yi,
F’ore-ofe pa mi mo
Fun mi l’aye lodo Re:
Iwo l’Orun at’ Asa
To okan isina mi;
Iwo l’Orisun ore
Ro ojo Re sori mi. Used With Tune: MAIDSTONE
Bugbe Re Ti L'ewa To