15908 | The Cyber Hymnal#15909 | 15910 |
Text: | Wa Eyin Olooto |
Translator: | Anonymous |
Tune: | [Wa eyin olooto, Layo at’ isegun] |
Composer: | John F. Wade |
Media: | MIDI file |
1 Wa eyin olooto, Layo at’ isegun,
Wa ka lo, wa ka lo si Betlehem,
Wa ka lo wo o! Oba awon Angeli.
Egbe:
E wa ka lo juba Re,
Ewa ka lo juba Re,
E wa ka lo juba
Kriti Oluwa.
2 Olodumare ni, Imole ododo,
Kosi korira inu Wundia;
Olorun paapaa ni, Ti a bi, ti a ko da. [Egbe]
3 Angeli e korin, Korin itoye re;
Ki gbogbo eda orun si gberin:
Ogo f’Olorun Li oke orun. [Egbe]
4 Ni tooto, a wole, F’Oba t’a bi loni;
Jesu iwo l’a wa nfi ogo fun:
’Wo omo Baba, To gba’ra wa wo. [Egbe]
Text Information | |
---|---|
First Line: | Wa eyin olooto, Layo at’ isegun |
Title: | Wa Eyin Olooto |
English Title: | O come, all ye faithful, joyful and triumphant |
Translator: | Anonymous |
Refrain First Line: | E wa ka lo juba Re |
Language: | Yoruba |
Copyright: | Public Domain |
Tune Information | |
---|---|
Name: | [Wa eyin olooto, Layo at’ isegun] |
Composer: | John F. Wade |
Key: | G Major or modal |
Copyright: | Public Domain |