15907 | The Cyber Hymnal#15908 | 15909 |
Text: | Sa Gbekele |
Author: | John H. Sammis |
Translator: | Anonymous |
Tune: | [Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re] |
Composer: | Daniel B. Towner |
Media: | MIDI file |
1 Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re,
Ona wa yio ti ma mole to!
Gba t’a ban se’fe Re, on y’o ma ba wa gbe,
At’ awon t’o ba gbeke won le.
Egbe:
Sa gbekele, ona miran kosi
Lati layo n’nu Jesu, jupe k’a gbekele.
2 Ko s’ohun to le de, loke tabi nile
Tole ko agbara re l’oju;
Iyemeji a’teru, ibanuje, ekun
Kole duro b’a ba gbekele. [Egbe]
3 Ko s’eru t’ale ru, ko s’aro t’a le pin
Ti ki y’o san ere re fun wa
Kosi arokan mo, tabi ifajuro
Sugbon ibukun b’aba gbekele. [Egbe]
4 A ko le f’enu so b’ife re ti po to
Titi a o f’ara wa rubo
Aanu ti o nfihan, at’ayo t’o nfun ni
Je t’awon to ba gbeke won le. [Egbe]
5 Nibi ‘pade ayo ka joko ni ese Re.
Tabi kajo rin ni ona Re.
Oun to so la o se, ibi to wu la o lo;
Kosi beru, ka sa gbekele. [Egbe]
Text Information | |
---|---|
First Line: | Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re |
Title: | Sa Gbekele |
English Title: | When we walk with the Lord in the light of his word |
Author: | John H. Sammis |
Translator: | Anonymous |
Refrain First Line: | Sa gbekele, ona miran kosi |
Language: | Yoruba |
Copyright: | Public Domain |
Tune Information | |
---|---|
Name: | [Gba t’a b’Oluwarin ninu ‘mole oro re] |
Composer: | Daniel B. Towner |
Key: | F Major or modal |
Copyright: | Public Domain |