15884. Itan Iyanu T'ife!

1 Itan iyanu t’ife! So fun mi lekan si
Itan iyanu tífe! Ti dun leti kikan
Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo
Elese, iwo ki yó gbo? Itan iyanu tífe!

Egbe:
Iyanu! Iyanu!
Iyanu! Itan iyanu t’ife

2 Itan iyanu t’ife! B’iwo tile sako
Itan iyanu t’ife! Sibe o npe loni
Lat’o oke kalfari, lati orisun didan ni
Lati ise-dale aiye; itan iyanu t’ife. [Egbe]

3 Itan iyanu t’ife! Jesu ni isimi
Itan iyanu t’ife! Fun awon oloto
T’o simi n’ilu nla orun, Pel’awon to saju wa lo
Nwon nko orin ayo orun, itan iyanu t’ife. [Egbe]

Text Information
First Line: Itan iyanu t’ife! So fun mi lekan si
Title: Itan Iyanu T'ife!
English Title: Wonderful story of love
Author: John M. Driver
Translator: Anonymous
Refrain First Line: Iyanu! Iyanu!
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: [Itan iyanu t’ife! So fun mi lekan si]
Composer: John M. Driver
Key: C Major
Copyright: Public Domain



Media
MIDI file: MIDI
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us
It looks like you are using an ad-blocker. Ad revenue helps keep us running. Please consider white-listing Hymnary.org or getting Hymnary Pro to eliminate ads entirely and help support Hymnary.org.