1 Ki lo le w’ese mi nu,
Ko so, leyin eje Jesu;
Ki l’tun le wo mi san,
Ko si, leyin eje Jesu.
Egbe:
A! eje yebiye
T’o mu mi fun bi sno
Ko s’isun miran mo,
Ko si lehin eje Jesu
2 Fun ’wenumo mi, nko ri
Nkan mi, lehin eje Jesu;
Ohun ti mo gbekele,
Fun ’dariji, l’eje Jesu. [Egbe]
3 Etutu f’ese ko si,
Ko si, lehin eje Jesu;
Ise rere kan ko si,
Ko si, lehin eje Jesu. [Egbe]
4 Gbogbo igbekele mi,
Ireti mi, l’eje Jesu;
Gbogbo ododo mi ni
Eje, kiki eje Jesu [Egbe]
Source: The Cyber Hymnal #15887